book.jayu.org

ǸJẸ́ NÍTÒÓTỌ́ ÌWỌ DI ÀTÚNBÍ NÍ TI OMI ATI TI Ẹ̀MÍ BÍ?

Paul C. Jong (지은이)

(도서출판)헵시바·2025-05-02

  • 348쪽
  • 148×210mm
  • 종교

로그인하면 내 서재에 추가할 수 있어요.

책 소개

Àkọ́lé ẹ̀kọ́ yìí gan an ni “lati di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí.” Ó ní ìpìlẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ yìí. Ní èdè mìíràn, ìwé yìí fi nyé wa gedegbe ohun tí àtúnbí jẹ́ ati bí a ti lè di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí ní ìbámu pẹlu Bibeli. Omi túmọ̀sí ìrìbọmi nínú odò Jọrdani Bibeli sì wipe gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa pátá ni ó ti rékọjá sórí Jesu nigbati Ó ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi. Johannu ni aṣojú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí Ó sì tún jẹ̀ àrọ́mọdọ́mọ Aaroni Olórí alufa. Aaroni gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ewúrẹ́ alààyè náà ó sì kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli ti ọdọdún sórí rẹ̀ ní ọjọ́ ètùtù. Èyí jẹ́ òjìjí ohun rere tí mbọ̀ wá. Ìrìbọmi Jesu ni àpẹẹrẹ ètò ìgbọ́wọ́lé. Jesu ṣe ìrìbọmi ní ìlànà ètò ìgbọ́wọ́lé lórí nínú odò Jọrdani. Nitoridi èyí Ó kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ aiyé yìí lọ nípasẹ̀ ìrìbọmi Rẹ̀. Ó sì kú lórí àgbélèbú lati san gbèsè ẹ̀ṣẹ̀. Ṣugbọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ Kristiẹni ni kò mọ ìdí tí Jesu fi ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi nínú odò Jọrdani. Ìrìbọmi Jesu ni kókó ọ̀rọ̀ ìwé yìí, ati apákan tí ó jẹ́ dandan sí ìhìnrere ti omi ati ti Ẹ̀mí. A lè di àtúnbí bí a bá nígbàgbọ́ sí ìrìbọmi ti Jesu ati ti ikú Rẹ̀ lórí igi àgbélèbú.

목차펼치기

ÀKÓJỌPỌ̀ Apá kìíní—Ìwàásù 1. A Gbọ́dọ̀ Kọ́kọ́ Mọ̀ nípa Ẹ̀ṣẹ̀ Wa ná lati lè ní Ìràpadà (Marku 7:8-9, 20-23) ---------------------------------------- 19 2. A Bí Ènìyàn Ní Ẹlẹ́ṣẹ̀ (Marku 7:20-23) ---------------------------------------------- 35 3. Bí A Bá Ṣe Ohun Gbogbo nípa Òfin, Ó lè Gbàwálà bí? (Luku 10:25-30) ---------------------------------------------- 47 4. Ìràpadà Aiyéraiyé (Johannu 8:1-12) -------------------------- 69 5. Ìrìbọmi Jesu ati Ètùtù fún Ẹ̀ṣẹ̀ (Matteu 3:13-17) ----------- 99 6. Jesu Kristi Wá nípasẹ̀ Omi, Ẹ̀jẹ̀, ati Ẹ̀mí (1 Johannu 5:1-12) ----------------------------------------- 145 7. Ìrìbọmi Jesu Ni Àpẹẹrẹ Ìgbàlà Fún Gbogbo Ẹlẹ́ṣẹ̀ (1 Peteru 3:20-22) ------------------------------------------ 179 8. Ìhìnrere ti Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ètùtù (Johannu 13:1-17) ------------------------------------------ 197 Apá Kejì—Àfikún 1. Ẹ̀rí Ìgbàlà ------------------------------------------------------- 259 2. Àfikún Àlàyé --------------------------------------------------- 279 3. Ìbéèrè ati Ìdáhùn ----------------------------------------------- 311

출처: 국립중앙도서관 서지정보

리뷰 남기기

로그인하면 리뷰를 남길 수 있어요.

리뷰 0개

아직 리뷰가 없어요.